1 Tímótíù 3:16 BMY

16 Láìṣiyè méjì, títóbi ní ohun ìjìnlẹ̀ ìwà-bí-Ọlọ́run:ẹni tí a fi hàn nínú ara,tí a dáláre nínú Ẹ̀mí,ti àwọn ańgẹ́lì rí,tí a wàásù rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè,tí a gbàgbọ́ nínú ayé,tí a sì gbà sókè sínú ògo.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 3

Wo 1 Tímótíù 3:16 ni o tọ