2 Pétérù 2:1 BMY

1 Ṣùgbọ́n àwọn wòlíì èké wà láàrin àwọn ènìyàn náà pẹ̀lú, gẹ́gẹ́ bí àwọn olùkọ́ni èké yóò ti wà láàrin yín. Wọn yóò yọ́lẹ̀ mú ẹ̀kọ́ òdì àti ègbé tọ̀ yín wa, àní tí yóò sẹ́ Olúwa tí ó rà wọ́n padà, wọ́n ó sì mú ìparun ti o yára kánkán wá sorí ara wọn.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:1 ni o tọ