2 Pétérù 2:2 BMY

2 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni yóò si máa tẹ̀lé ọ̀nà ìtìjú wọn, tí wọn yóò sì mú kí ọ̀nà òtítọ́ di ìsọ̀rọ̀-òdì-sí.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:2 ni o tọ