2 Pétérù 2:14 BMY

14 Ojú wọn kún fún panságà, wọn kò sì dẹ́kun ẹ̀sẹ̀ dídá; wọ̀n ń tan àwọn tí kò dúró ṣinṣin; wọ́n yege nínú iṣẹ́ wọ̀bìà, ẹni ègún ni wọ́n.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:14 ni o tọ