2 Pétérù 2:15 BMY

15 Wọ́n kọ ọ̀nà tí ó tọ́ sílẹ̀, wọ́n sì sáko lọ, wọ́n tẹ̀lé ọ̀ná Bálámù ọmọ Béórì, ẹni tó fẹ́ràn èrè àìsòdodo.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:15 ni o tọ