2 Pétérù 2:22 BMY

22 Òwe òtítọ́ náà ṣẹ sí wọn lára: “Ajá tún padà sí èébì ara rẹ̀; àti ẹlẹ́dẹ̀ tí a ti wẹ̀ mọ́ tún padà ń yíràá nínú ẹrọ̀fọ̀.”

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:22 ni o tọ