2 Pétérù 3:1 BMY

1 Olùfẹ́, èyí ni ìwé kejì tí mo ń kọ sí yín, nínú méjèèjì náà ni èmi ń ru èrò inú yín sókè nípa rírán yín létí;

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:1 ni o tọ