2 Pétérù 3:2 BMY

2 Kí ẹ̀yín lè máa rántí ọ̀rọ̀ tí a ti ẹnu àwọn wòlíì mímọ́ sọ ṣáájú, àti òfin Olúwa àti Olùgbàlà wa láti ọ̀dọ̀ àwọn àpósítélì yín.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:2 ni o tọ