2 Pétérù 3:14 BMY

14 Nítorí náà, olùfẹ́, bí ẹ̀yin ti ń retí irú nǹkan wọ̀nyí, ẹ múra gírí, kí a lè bá yín ní àlàáfíà ní àìlábàwọ́n, àti ní àìlábùkù lójú rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:14 ni o tọ