2 Pétérù 3:15 BMY

15 Kí ẹ sì máa kà á sí pé, sùúrù Olúwa wa ìgbàlà ni; bí Pọ́ọ̀lù pẹ̀lú arákùnrin wa olùfẹ́, ti kọ̀wé sí yín gẹ́gẹ́ bí ọgbọ́n tí a fi fún un.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:15 ni o tọ