2 Pétérù 3:17 BMY

17 Nítorí náà ẹ́yín olùfẹ́, bí ẹ̀yin ti mọ nǹkan wọ̀nyí tẹ́lẹ̀, ẹ máa kiyé sára, kí a má baà fi ìsìnà àwọn ènìyàn búburú fà yín lọ, kí ẹ sì ṣubú kúrò ní ìdúró-ṣinṣin yín.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:17 ni o tọ