2 Pétérù 3:18 BMY

18 Ṣùgbọ́n ẹ máa dàgbà nínú oore-ọ̀fẹ́ àti nínú ìmọ̀ Olúwa àti Olùgbàlà wa Jésù Kírísítì; ẹni tí ògo wà fún nísinsìn yìí àti títí láé. Àmín.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:18 ni o tọ