2 Tẹsalóníkà 1:11 BMY

11 Nítorí èyí, àwa pẹ̀lú ń gbàdúrà fún un yín nígbà gbogbo, pé kí Ọlọ́run wa kí ó lè kà yín yẹ fún ìpè rẹ̀, àti pé nípa agbára rẹ̀, òun yóò mú gbogbo èrò rere yín sẹ àti gbogbo ohun tí ìgbàgbọ́ bá rú jáde.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 1

Wo 2 Tẹsalóníkà 1:11 ni o tọ