2 Tẹsalóníkà 1:3 BMY

3 Ó yẹ kí a máa dúpẹ́ nígbà gbogbo nítorí yín, ará, àní gẹ́gẹ́ bí ó ti yẹ, nítorí pé ìgbàgbọ́ yín ń dàgbà gidigidi, àti ìfẹ́ olúkúlùkù yín gbogbo sí ara yín ń di púpọ̀.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 1

Wo 2 Tẹsalóníkà 1:3 ni o tọ