2 Tẹsalóníkà 1:5 BMY

5 Àwọn nǹkan wọ̀nyí jẹ́ ẹ̀rí pé òdodo ni ìdájọ́ Ọlọ́run àti pé ní torí èyí ni a ó kà yín yẹ fún ìjọba Ọlọ́run, nítorí èyí tí ẹ̀yin pẹ̀lú ṣe ń jìyà.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 1

Wo 2 Tẹsalóníkà 1:5 ni o tọ