2 Tẹsalóníkà 1:7 BMY

7 Òun yóò sì fi ìtura fún ẹ̀yin tí a ti pọ́n lójú àti fún àwa náà pẹ̀lú. Èyí yóò sì se nígbà ìfarahàn Jésù Olúwa láti ọ̀run wá fún wá nínú ọwọ́ iná pẹ̀lú àwọn ańgẹ́lì alágbára.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 1

Wo 2 Tẹsalóníkà 1:7 ni o tọ