2 Tẹsalóníkà 2:16 BMY

16 Ǹjẹ́ kí Jésù Kírísítì Olúwa wa tìkalára rẹ̀, àti Ọlọ́run baba wa, ẹni to ti fẹ́ wa, tí ó sì ti fi ìtùnú àìnípẹ̀kun àti ìrètí rere nípa oore-ọ̀fẹ́ fún wa.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 2

Wo 2 Tẹsalóníkà 2:16 ni o tọ