2 Tẹsalóníkà 2:2 BMY

2 kí ọkàn yín má ṣe àìbalẹ̀, tàbí kí ẹ má ṣe jáyà nípa àṣọtẹ́lẹ̀, ìròyìn tàbí lẹ́tà tí ó lè farajọ èyí tí ó le wá láti ọ̀dọ̀ wa, tí yóò máa wí pé ọjọ́ Olúwa ti dé ná.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 2

Wo 2 Tẹsalóníkà 2:2 ni o tọ