2 Tẹsalóníkà 2:4 BMY

4 Òun yóò lòdì sí, yóò sì gbé ara rẹ̀ ga sí gbogbo ohun tí a ń pè ní Ọlọ́run tàbí tí a ń sìn, dé ibi pé yóò gbé ara rẹ̀ jókòó nínú tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run, tí yóò sì ń pe ara rẹ̀ ní Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 2

Wo 2 Tẹsalóníkà 2:4 ni o tọ