2 Tímótíù 1:18 BMY

18 Kí Olúwa fi fún un kí ó lè rí àánú lọ́dọ̀ Olúwa ni ọjọ́ náà! Ìwọ tìkararẹ sáà mọ̀ ọ̀nà gbogbo tí ó gbà rànmí lọ́wọ́ ni Éfésù.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 1

Wo 2 Tímótíù 1:18 ni o tọ