2 Tímótíù 1:8 BMY

8 Nítorí náà, má ṣe tijú láti jẹ̀rìí nípa Olúwa wa, tàbí èmi òǹdè rẹ̀; ṣùgbọ́n kí ìwọ ṣe alábàápín nínú ìpọ́njú ìyìnrere nípa agbára Ọlọ́run,

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 1

Wo 2 Tímótíù 1:8 ni o tọ