2 Tímótíù 2:10 BMY

10 Nítorí náà mo ń faradà ohun gbogbo nítorí àwọn àyànfẹ́; kí àwọn náà pẹ̀lú lè ní ìgbàlà tí ń bẹ nínú Kírísítì Jésù pẹ̀lú ògo ayérayé.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 2

Wo 2 Tímótíù 2:10 ni o tọ