2 Tímótíù 2:7 BMY

7 Ronú lórí ohun ti èmi ń sọ; nítorí Olúwa yóò fún ọ lóye nínú ohun gbogbo.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 2

Wo 2 Tímótíù 2:7 ni o tọ