2 Tímótíù 3:16 BMY

16 Gbogbo ìwé-Mímọ́ ni ó ní ìmísí Ọlọ́run tí ó sì ní èrè fún ẹ̀kọ́, fún ìbániwí, fún ìtọ́ni, fún ìkọ́ni tí ó wà nínú òdodo.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 3

Wo 2 Tímótíù 3:16 ni o tọ