2 Tímótíù 4:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n Olúwa gba ẹjọ́ mi rò, ó sì fún mi lágbára; pé nipasẹ̀ mi kí a lè wàásù náà ní àwàjálẹ̀, àti pé kí gbogbo àwọn aláìkọlà lè gbọ́; a sì gbà mí kúrò lẹ́nu kìnìún náà.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 4

Wo 2 Tímótíù 4:17 ni o tọ