2 Tímótíù 4:21 BMY

21 Sa ipá rẹ láti tètè wá ṣáájú ìgbà òtútù. Éúbúlù kí ọ, àti Páúdánì, àti Línù, Kíláúdíà, àti gbogbo àwọn ará-kùnrin.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 4

Wo 2 Tímótíù 4:21 ni o tọ