Gálátíà 1:13 BMY

13 Nítorí ẹ̀yin ti gbúrò ìwà-ayé mi nígbà àtijọ́ nínú ìsìn àwọn Júù, bí mo tí ṣe inúnibíni sí ìjọ ènìyàn Ọlọ́run rékọjá ààlà, tí mo sì lépa láti bà á jẹ́:

Ka pipe ipin Gálátíà 1

Wo Gálátíà 1:13 ni o tọ