Gálátíà 1:18 BMY

18 Lẹ́yìn ọdún mẹ́ta, nígbà náà ni mo gòkè lọ sì Jerúsálémù láti lọ kì Pétérù, mo sì gbé ọ̀dọ̀ rẹ̀ ní ìjọ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún,

Ka pipe ipin Gálátíà 1

Wo Gálátíà 1:18 ni o tọ