Gálátíà 1:23 BMY

23 Wọ́n kàn gbọ́ ìròyìn wí pé, “Ẹni tí ó tí ń ṣe inúnibíni sí wa rí, ní ìsinsìn yìí ti ń wàásù ìgbàgbọ́ náà tí ó ti gbìyànjú láti bàjẹ́ nígbà kan rí.”

Ka pipe ipin Gálátíà 1

Wo Gálátíà 1:23 ni o tọ