Gálátíà 3:11 BMY

11 Nítorí ó dánilójú pé, a kò dá ẹnìkẹ́ni láre níwájú Ọlọ́run nípa iṣẹ́ òfin: nítorí pé, olódodo yóò yè nípa ìgbàgbọ́.”

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:11 ni o tọ