Gálátíà 3:21 BMY

21 Nítorí náà òfín ha lòdì sí àwọn ìlérí Ọlọ́run bí? Kí a má rí i; Nítorí ìbá ṣe pé a ti fi òfin kan fún ni tí ó lágbára láti sọni di ààyè nítòótọ́ òdodo ìbá ti tipasẹ̀ òfin wà.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:21 ni o tọ