Gálátíà 3:27 BMY

27 Nítorí pé iye ẹ̀yin tí a ti baptisti sínú Kírísítì ti gbé Kírísítì wọ̀.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:27 ni o tọ