Gálátíà 5:1 BMY

1 Nítorí náà, ẹ dúró ṣinṣin nínú òmìnira náà èyí tí Kírísítì fi sọ wá di òmìnira, kí ẹ má sì ṣe tún fi ọrùn bọ̀ àjàgà ẹrú mọ́.

Ka pipe ipin Gálátíà 5

Wo Gálátíà 5:1 ni o tọ