Gálátíà 6:12 BMY

12 Iye àwọn tí ń fẹ́ ṣe àṣehàn ni ara wọn ń rọ yín láti kọlà; kìkì nítorí pé kí a má ba à ṣe inúnibíni sí wọn nítorí àgbélébùú Kírísítì.

Ka pipe ipin Gálátíà 6

Wo Gálátíà 6:12 ni o tọ