Kólósè 1:2 BMY

2 Sí àwọn ẹni mímọ́ àti àwọn arákùnrin nínú Kírísítì tí wọ́n ń gbé ní ìlú Kólósè.Oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà fún-un yín láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa.

Ka pipe ipin Kólósè 1

Wo Kólósè 1:2 ni o tọ