Kólósè 3:25 BMY

25 Ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe àìṣòdodo, yóò gbàá padà nítorí àìṣòdodo náà tí ó ti ṣe: kò sì sí ojúṣáájú.

Ka pipe ipin Kólósè 3

Wo Kólósè 3:25 ni o tọ