Kólósè 4:16 BMY

16 Nígbà tí a bá sì ka ìwé yìí ní àárin yín tan, kí ẹ mú kí a kà á pẹ̀lú nínú ìjọ Laodékíà; ẹ̀yin pẹ̀lú sì ka èyí tí ó ti Laodékíà wá.

Ka pipe ipin Kólósè 4

Wo Kólósè 4:16 ni o tọ