Àwọn Adájọ́ 1:11 BM

11 Nígbà tí wọ́n kúrò níbẹ̀, wọ́n lọ gbógun ti ìlú Debiri. (Kiriati Seferi ni orúkọ tí wọ́n ń pe Debiri tẹ́lẹ̀.)

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1

Wo Àwọn Adájọ́ 1:11 ni o tọ