18 Àwọn ọmọ Juda ṣẹgun ìlú Gasa ati àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè rẹ̀. Wọ́n ṣẹgun ìlú Aṣikeloni ati Ekironi ati àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè wọn.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1
Wo Àwọn Adájọ́ 1:18 ni o tọ