2 OLUWA dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yà Juda ni kí ó kọ́ dojú kọ wọ́n, nítorí pé, mo ti fi ilẹ̀ náà lé wọn lọ́wọ́.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1
Wo Àwọn Adájọ́ 1:2 ni o tọ