Àwọn Adájọ́ 1:24 BM

24 Àwọn amí náà rí ọkunrin kan tí ń jáde bọ̀ láti inú ìlú náà, wọ́n wí fún un pé, “Jọ̀wọ́, fi ọ̀nà tí a óo gbà wọ ìlú yìí hàn wá, a óo sì ṣe ọ́ lóore.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1

Wo Àwọn Adájọ́ 1:24 ni o tọ