Àwọn Adájọ́ 1:28 BM

28 Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli di alágbára sí i, wọ́n ń fi tipátipá kó àwọn ará Kenaani ṣiṣẹ́, ṣugbọn wọn kò lé wọn kúrò láàrin wọn patapata.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1

Wo Àwọn Adájọ́ 1:28 ni o tọ