Àwọn Adájọ́ 1:31 BM

31 Àwọn ọmọ Aṣeri náà kò lé àwọn wọnyi jáde: àwọn ará Ako ati àwọn ará Sidoni, àwọn ará Ahilabu ati àwọn ará Akisibu, àwọn ará Heliba ati àwọn ará Afeki, ati àwọn ará Rehobu.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1

Wo Àwọn Adájọ́ 1:31 ni o tọ