9 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbógun ti àwọn ará ilẹ̀ Kenaani tí wọ́n ń gbé orí òkè, ati ìhà gúsù tí à ń pè ní Nẹgẹbu, ati àwọn tí wọn ń gbé ẹsẹ̀ òkè náà pẹlu.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1
Wo Àwọn Adájọ́ 1:9 ni o tọ