11 OLUWA bá dá àwọn ọmọ Israẹli lóhùn, ó ní, “Ṣebí èmi ni mo gbà yín lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti ati àwọn ara Amori, ati àwọn ará Amoni ati àwọn ará Filistia.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 10
Wo Àwọn Adájọ́ 10:11 ni o tọ