Àwọn Adájọ́ 10:8 BM

8 Odidi ọdún mejidinlogun ni wọ́n fi ni àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà ní òdìkejì odò Jọdani, ní Gileadi lára. Gileadi yìí wà ní ilẹ̀ àwọn ará Amoni.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 10

Wo Àwọn Adájọ́ 10:8 ni o tọ