Àwọn Adájọ́ 11:27 BM

27 Nítorí náà, n kò ṣẹ̀ ọ́ rárá, ìwọ ni o ṣẹ̀ mí, nítorí pé o gbógun tì mí. Kí OLUWA onídàájọ́ dájọ́ lónìí láàrin àwọn ọmọ Israẹli ati Amoni.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:27 ni o tọ