Àwọn Adájọ́ 11:29 BM

29 Ẹ̀mí OLUWA bá bà lé Jẹfuta, ó bá kọjá láàrin Gileadi ati Manase, ó lọ sí Misipa ní ilẹ̀ Gileadi, láti ibẹ̀ ni ó ti lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Amoni.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:29 ni o tọ