Àwọn Adájọ́ 11:34 BM

34 Jẹfuta bá pada sí ilẹ̀ rẹ̀ nì Misipa, bí ó ti ń wọ̀lú bọ̀, ọmọ rẹ̀ obinrin wá pàdé rẹ̀ pẹlu ìlù ati ijó, ọmọbinrin yìí sì ni ọmọ kan ṣoṣo tí ó bí.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:34 ni o tọ