11 Manoa bá gbéra, ó bá tẹ̀lé iyawo rẹ̀ lọ sọ́dọ̀ ọkunrin náà, ó bi í pé, “Ṣé ìwọ ni o bá obinrin yìí sọ̀rọ̀?”Ọkunrin náà dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13
Wo Àwọn Adájọ́ 13:11 ni o tọ